Librería Samer Atenea
Librería Aciertas (Toledo)
Kálamo Books
Librería Perelló (Valencia)
Librería Elías (Asturias)
Donde los libros
Librería Kolima (Madrid)
Librería Proteo (Málaga)
5:2 And he opened his mouth, and taught them, saying,5:2 O si yà ẹnu rẹ̀, o si kọ́ wọn, wipe:5:3 Blessed are the poor in spirit: for theirs is the kingdom of heaven.5:3 Alabukún-fun li awọn talaka ni ẹmi: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.5:4 Blessed are they that mourn: for they shall be comforted.5:4 Alabukún-fun li awọn ti nsọ̀fọ: nitori nwọn o ni itunu.5:5 Blessed are the meek: for they shall inherit the earth.5:5 Alabukún-fun li awọn ọlọkàn-tutu: nitori nwọn o jogún aiye.5:6 Blessed are they which do hunger and thirst after righteousness: for they shall be filled.5:6 Alabukún-fun li awọn ti ebi npa ati ti ongbẹ ngbẹ si ododo: nitori nwọn o yo.