Lateefat Odunuga / Oluwaseyi Fasunhan
Librería Samer Atenea
Kálamo Books
Librería Perelló (Valencia)
Librería Elías (Asturias)
Donde los libros
Librería Kolima (Madrid)
Librería Proteo (Málaga)
Ní òye àyọ̀ tó wà nínú ìṣẹ̀dá pẹ̀lú ’TỌ́MÌ ÀTI IRÚGBÌN KÉKERÉ’. Ìtàn aládùn yìí ń pe àwọn òǹkàwé lọmọdé, bẹ̀rẹ̀ láti ọmọ òòjọ́ sí ọmọ ọdún márùn-ún sí ìgbé ayé Tọ́mì, tí ó jẹ́ aláwáfín ọmọdé-kùnrin, níbi tí ó ti ṣe àwárí idán tí ó sodo sínú gbígbin irúgbìn kékeré àti bí ó ṣe fojú rí ìdàgbàsókè ńlá tí ó dé bá irúgbìn náà nípa yíyírapadà láti di òdòdó alárinrin. Ìwé yìí ṣe àfihàn tí ó pé nípa àwọn ohun àrà tí ó wà nínú iṣẹ̀dá fún àwọn ọmọdé pẹ̀lú àwọn àwòrán aláràǹbarà.