LIBROS DEL AUTOR: adeola oreoluwa adefeso

1 resultados para LIBROS DEL AUTOR: adeola oreoluwa adefeso

adeola oreoluwa adefeso Eliminar filtro Quitar filtros
  • Ọlọ́run, Níbo Lo Wá?
    Adeola Oreoluwa Adefeso
    A bí Adéọlá Ọrẹolúwa Adéfẹ̀sọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ṣe èwe rẹ̀ nínú ayọ̀ àti ìdùnnú. Àwọn òbí rẹ̀ àgbà ní ìdílé ìyá ló tọ́ ọ dàgbà pẹ̀lú ìfẹ́ tó wàyàmì àti ẹ̀kọ́ ìwé tó yè kooro, òun náà sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akọrin agbègbè ibẹ̀. Ṣùgbọ́n nǹkan yí bìrí nígbà tí ó kó sí wàhálà abẹ́ ilé látàrí ìjìyà tí ó ń rí láti ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀. Inú làásìgbò ìjìyà ara àti ọkàn...
    Disponible

    13,03 €